Bóòlù mi tí ó Púpa

My Ball That's Red

My Red Ball


By Marion Drew

Illustrated by Marion Drew

Translated by
Victor & Blessing Williamson
Victor Williamson
Marion DrewFrom source www.africanstorybook.org, paleng.weebly.com

Available under Creative Commons-Attribution 4.0

In Language

Bóòlù.
This ball.
A ball.
EbonicsYorùbáEnglish
1
Bóòlù mi.
It's my ball.
My ball.
EbonicsYorùbáEnglish
2
Bóòlù mi tí ó púpa.
It's my big ball.
My big ball.
EbonicsYorùbáEnglish
3
Bóòlù mi tí ó púpa àti tí ó tóbi.
It's my big red ball.
My big red ball.
EbonicsYorùbáEnglish
4
Mo ń fi ẹsẹ̀ gbá.
I kick it.
I kick.
EbonicsYorùbáEnglish
5
Mo ń fi ẹsẹ̀ gbá bóòlù mi.
I kick my ball.
I kick my ball.
EbonicsYorùbáEnglish
6
Mo ń fi ẹsẹ̀ gbá bóòlù mi tí ó púpa.
I kick my red ball.
I kick my red ball.
EbonicsYorùbáEnglish
7
Mo ń fi agbára fi ẹsẹ̀ gbá bóòlù mi tí ó púpa!
I kick my big red ball.
I kick my big red ball.
EbonicsYorùbáEnglish
8
Níbo lo wà?
Where it go?
Where is it?
EbonicsYorùbáEnglish
9
Níbo ni bóòlù mi wà?
Where my ball go?
Where's my ball?
EbonicsYorùbáEnglish
10
Níbo ni bóòlù mi wà nísínsinyìí?
Where my ball at now?
Where's my ball now?
EbonicsYorùbáEnglish
11
Níbo ni bóòlù mi tí ó púpa wà nísínsinyìí?
Where my red ball at now?
Where's my red ball now?
EbonicsYorùbáEnglish
12
O wà lókè.
It went up.
It's up.
EbonicsYorùbáEnglish
13
O wà lókè lókè.
It's way up.
It's high up.
EbonicsYorùbáEnglish
14
O wà lókè ní ọ̀run.
There it go up high in the sky.
It's high up in the sky.
EbonicsYorùbáEnglish
15
Ó wà lókè lókè ní ọ̀run.

Ó wà sórí òṣùpá.

Ó ti lọ!
It done gone way up high in the sky.

It be on the moon.

It done left.
It's very high up in the sky.

It's over the moon.

It's gone.
EbonicsYorùbáEnglish
16
The end.
My Ball That's Red