Mo Fẹ́ràn Ìwé KíkàI Love to be ReadingI Love ReadingByIllustrated by Wiehan de Jager, Vusi MalindiTranslated by
|
|
In Language |
|
Mo fẹ́ràn láti kàwé.
I love to be reading.
I love to read.
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
1
|
|
Mo máa ń kàwé pẹ̀lú ọ̀rẹ́
mi.
Me and my friend be reading.
I read with my friend.
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
2
|
|
Olùkọ́ mi ń ràn mí lọ́wọ́ láti kàwé.
My teacher help me read.
My teacher helps me to read.
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
3
|
|
Tani mo lè kàwé fún?
Who I'm gonna read to?
Who am I going to read to?
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
4
|
|
Mo máa ń kàwé pẹ̀lú àwọn ọ̀rẹ́ mi.
I'm a read with my friends.
I'll read with my friends.
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
5
|
|
Tani mo lè kàwé fún?
Who I'm a read to?
Who am I going to read to?
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
6
|
|
Bàbá mi àti Bàbá bàbá mi ń ṣiṣẹ́
My dad and grandad working.
My father and grandfather are working.
|
|
EbonicsYorùbáEnglish
7
|
|
Tani mo lè kàwé fún?
Mo lè kàwé fúnara mi
Who I'm a read to?
I'm finna read all by myself.
Who am I going to read to?
I'll read to myself. |
|
EbonicsYorùbáEnglish
8
|
|
The end. |