Ìdí tí wọn kò sin Ajao

Why Ajao Ain't Buried

Why Ajao Was Not Buried


By Taiwo Ẹhinẹni

Illustrated by Jesse Breytenbach

Translated by
Taiwo Ẹhinẹni
Victor Williamson
Taiwo ẸhinẹniFrom source www.africanstorybook.org

Available under Creative Commons-Attribution 4.0

In Language

Ajao, àdán kan, sùn sí ilé rẹ̀ nínú àárẹ̀.

Kòsí ẹnikẹ́ni tí ó yojú sí i.
Ajao the bat real sick, laid out in his crib.

Wasn't no one to care for him.
Ajao, a bat, lay in his house very ill.

There was no one to attend to him.
EbonicsYorùbáEnglish
1
Lẹ́yìn náà, Ajao kú.
So, Ajao died.
Then, Ajao died.
EbonicsYorùbáEnglish
2
Àwọn aládùúgbò ní, "Ajao ti kú, a gbọdọ̀ pe àwọn ẹbí rẹ̀ láti wá sín."
The neighbours be like, "Ajao dead and gone. We better tell his family so they might can come bury him."
The neighbours said, "Ajao is dead. We must call his relations to come and bury him."
EbonicsYorùbáEnglish
3
Àwọn aládùúgbò lọ pe àwọn ẹyẹ pé, "Ìkan lára yín ti kú."
Them neighbours went to the birds shouting, "Your relative dead and gone."
The neighbours went and called the birds saying, "A relative of yours is dead.
EbonicsYorùbáEnglish
4
Àwọn ẹyẹ wá, wọ́n sì ri pé Ajao ni.

Wọ́n ní, "Ẹranko yìí kì í ṣe ara ẹbí wa."
The birds come and see that it be Ajao.

They was like, "This animal ain't part of our family."
The birds came and saw that it was Ajao.

They said, "This animal is not part of our family."
EbonicsYorùbáEnglish
5
"Gbogbo ẹbí wa ní ìyẹ́ ṣùgbọ́n Ajao kò ní nǹkankan. Nítorí náà, kì í ṣe ara wa."

Àwọn ẹyẹ náà sálọ
"Everybody in our family got feathers, and Ajao don't. So he not one of us."

So them birds left there.
"All our family have feathers but Ajao has none. So, he is not one of us."

The birds went away.
EbonicsYorùbáEnglish
6
Àwọn aládùúgbò ronú papọ̀, wọ́n ní, "Òòtọ́ ni àwọn ẹyẹ sọ. Ajao kò ní ìyẹ́. Nítorí náà, kì í ṣe ara wọn."
Them neighbours come together. They agree, "Those birds right, Ajao don't got feathers. So he can't be they relative."
The neighbours reasoned together. They agreed, "The birds are right. Ajao has no feathers. So, he is not their relative."
EbonicsYorùbáEnglish
7
Ìkan lára wọn ní, "Ó gbọdọ̀ jẹ́ ìkan lára àwọn eku. Ó jọ wọ́n."
One say, "He got to be part of the rat family. He look like them."
One of them said, "He must be part of the family of rats. He looks like them."
EbonicsYorùbáEnglish
8
Àwọn aládùúgbò lọ pe àwọn eku pé, "Ìkan lára àwọn ẹbí yín ti kú."
The neighbours went to them rats shouting, "One of your family dead and gone."
The neighbours went and called the rats saying, "One of your family is dead."
EbonicsYorùbáEnglish
9
Àwọn eku wá, wọ́n sì ri pé Ajao ni. The rats came and saw that it was Ajao.

Wọ́n ní, "Ẹranko yìí kì í ṣe ara ẹbí wa."
Them rats come and see that it be Ajao.

They was like, "This animal ain't part of our family."
The rats came and saw that it was Ajao.

They said, "This animal is not part of our family."
EbonicsYorùbáEnglish
10
"Gbogbo ẹbí wa ní ìrù ṣùgbọ́n Ajao kò ní ìrù."

Àwọn eku náà rìn lọ.
"All of us got tails, and Ajao don't got one."

So them rats left there.
"Everyone in our family has a tail. Ajao has no tail."

The rats went away.
EbonicsYorùbáEnglish
11
A kò rí ẹbí fún Ajao, ó sì wà bẹ́ẹ̀ láì sí ẹni tí yóò sín in.
Wasn't no family found for Ajao so they left him not buried.
No relations were found for Ajao and he remained unburied.
EbonicsYorùbáEnglish
12
The end.
Why Ajao Ain't Buried