Ọkùnrin gíga púpọ̀ kan

A Man So Tall

A Very Tall Man


By Cornelius Gulere

Illustrated by Catherine Groenewald

Translated by
Taiwo Ẹhinẹni
Victor Williamson
Cornelius GulereFrom source www.africanstorybook.org, www.ugcla.org

Available under Creative Commons-Attribution 4.0

In Language

Ọkọ́ rẹ̀ kúrú jù.
His hoe too short.
His hoe was too short.
EbonicsYorùbáEnglish
1
Ọ̀nà ilẹ̀kùn rẹ̀ kéré jù.
His doorway be too low.
His doorway was too low.
EbonicsYorùbáEnglish
2
Ibùsùn rẹ̀ kúrú jù.
His bed way too short.
His bed was too short.
EbonicsYorùbáEnglish
3
Kẹ̀kẹ́ rẹ̀ kúrú jù.
His bike so little for him.
His bicycle was too short.
EbonicsYorùbáEnglish
4
Ọkùnrin yìí ga jù!
This man here just too tall!
This man was too tall!
EbonicsYorùbáEnglish
5
Ó ṣe ọwọ ọkọ́ gígùn púpọ̀ kan.
He made a handle for his hoe big enough for him.
He made a very long hoe handle.
EbonicsYorùbáEnglish
6
Ó ṣe ara ilẹ̀kùn gíga púpọ̀.
He made his doorway higher.
He made very high door frames.
EbonicsYorùbáEnglish
7
Ó ṣe ibùsùn gígùn púpọ̀ kan.
He made this super long bed.
He made a very long bed.
EbonicsYorùbáEnglish
8
Ó ra kẹ̀kẹ́ gíga púpọ̀ kan.
He got a tall bike for his self.
He bought a very high bicycle.
EbonicsYorùbáEnglish
9
Ó jòkó lórí aga gíga kan. Ó jẹun pẹ̀lú fọ́ọ̀kì gígùn kan.
He sat on a chair high enough for him. He used a long fork to eat with.
He sat on a very high chair. He ate with a very long fork.
EbonicsYorùbáEnglish
10
Ó kúrò ní ilé rẹ̀, o sì gbé ní igbó ńlá kan.

Ó gbé fún ọdún púpọ̀.
He ditched his house to go live in a big forest.

He lived a real long time.
He left his house and lived in a big forest.

He lived for many years.
EbonicsYorùbáEnglish
11
The end.
A Man So Tall