Ọjọ́ tí Òòrùn rin ìrinajò

Day Sun Left

Day the Sun Went Away


By Khothatso Ranoosi, Marion Drew

Illustrated by Jesse Breytenbach

Translated by
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
Victor Williamson
Khothatso Ranoosi, Marion DrewFrom source www.africanstorybook.org, paleng.weebly.com

Available under Creative Commons-Attribution 4.0

In Language

Òòrùn pinnu láti lọ kí àbúrò rẹ̀ obìnrin, òṣùpá.

Òṣùpá ń gbé ní òdìkejì òfuurufú.

"Mo máa padà dé láìpẹ́", Òòrùn sọ fún ìkuukù.
Mama Sun want to go visit her sister moon.

Sister Moon live across the sky.

"I'm gonna be back," Sun tells clouds.
Mother Sun decided to visit her sister, the moon.

Sister Moon lives on the other side of the sky.

“I will be back soon,” said Sun to the clouds.
EbonicsYorùbáEnglish
1
Kò pẹ́ tí Òòrùn jáde lọ, àwọn òkè wé gèlè funfun.
When Sun left, mountains wore they white scarves.
When Sun left, the mountains put on their white scarves.
EbonicsYorùbáEnglish
2
Afẹ́fẹ́ ń ṣàríyànjiyàn pẹ̀lú àwọn igi.

Inú bí àwọn igi.

Wọ́n fọ́n gbogbo ewé wọn ká ibi gbogbo.
Wind got into a fight with trees.

Trees got angry.

They threw they leaves every which way.
Wind had an argument with the trees.

The trees became angry.

They threw their leaves all over the place.
EbonicsYorùbáEnglish
3
Òfuurufú bẹ̀rẹ̀ sí i kùn.

Ó yírá padà sí òféèfé.
Sky started grumbling.

She got grey.
The sky started to grumble.

She turned grey.
EbonicsYorùbáEnglish
4
Inú àwọn ìkuukù kò dùn láti rí ohun tí ó ń ṣẹlẹ̀.

Wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún.

Ẹkún púpọ̀ wà.
Clouds was hurt seeing all this.

They started crying.

A lot of tears was there.
The clouds were sad to see all this.

They started crying.

There were many tears.
EbonicsYorùbáEnglish
5
Gbogbo àgbáyé bẹ̀rẹ̀ sí í rì wọnú omi lọ.
Earth started sinking with all that water.
The whole world began to sink under water.
EbonicsYorùbáEnglish
6
Bẹ́ẹ̀ kẹ̀dẹ̀ ré, ní apá kejì òfuurufú, Òòrùn ti ṣetán láti kúrò lọ́dọ̀ àbúrò rẹ̀.

Wọ́n fẹnu konu, ó kí òṣùpá pé ó dìgbà ó sì padà sí ilé.
Sun across the sky ready now to leave her sister.

She kissed moon goodbye and went home.
Meanwhile on the other side of the sky, Sun was ready to leave her sister.

She kissed the moon goodbye and went home.
EbonicsYorùbáEnglish
7
Inú òfuurufù dùn púpọ̀ láti rí Òòrùn tó bẹ́ẹ̀ tí ó sì yípadà sí àwọ̀ búlù.

Àwọn òkè wọ àsọ aláwọ̀-ewé wọn.
Sky was so happy once she saw Sun that she shown bright blue.

Mountains wore they pretty green dresses.
Sky was so happy to see Sun that she turned bright blue.

The mountains put on their pretty green dresses.
EbonicsYorùbáEnglish
8
Afẹ́fẹ́ lọ sùn.

Awọn igi na ẹ̀ka wọn, wọ́n sì rẹ́rìn-ín.
Wind went to slept.

Trees spread out they branches and smiled.
The wind went to sleep.

The trees stretched their branches and smiled.
EbonicsYorùbáEnglish
9
nú àwọn ìkuukù dùn láti rí Òòrùn padà.

Wọ́n jádé lọ ṣeré.
Clouds was so happy to see mama Sun again.

They went to play.
The clouds were very happy to see mother Sun again.

They went away to play.
EbonicsYorùbáEnglish
10
Ọ̀pọ̀ àwọn ewéko kéèkèèké hù jáde láti inú ilẹ̀ láti ṣe "báwo ni?"

Gbogbo àgbáyé ń tàn yinrin.
A whole bunch of small plants started sprouting out the earth saying, "Hello"

All the world sparkled.
Lots of little plants popped out of the earth to say, “Hello.”

The whole world sparkled.
EbonicsYorùbáEnglish
11
Òòrún tan ìtànṣán rẹ̀ sí ibi gbogbo.

Pẹ̀lú ayọ̀, ó ní "Mo wí fún yín pé n óò padà wá."
Mama Sun shined her light all over.

"I told you I'd be back," she beamed.
Mother Sun shone her light everywhere.

"I told you I would be back," she beamed.
EbonicsYorùbáEnglish
12
The end.
Day Sun Left