Kíka Àwọn Ẹranko

Counting Them Animals

Counting Animals


By Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare Verbeek

Illustrated by Rob Owen

Translated by
Ṣẹ́gun Ṣóẹ̀tán
Victor Williamson
Zanele Buthelezi, Thembani Dladla, Clare VerbeekFrom source www.africanstorybook.org, www.akdn.org

Available under Creative Commons-Attribution 3.0

In Language

Erin kan fẹ́ lọ mu omi.
One elephant going for a drink of water.
One elephant is going to drink water.
EbonicsYorùbáEnglish
1
Àgùfọn méjì fẹ́ lọ mu omi.
Two giraffes going for a drink of water.
Two giraffes are going to drink water.
EbonicsYorùbáEnglish
2
Ẹfọ̀n mẹ́ta àti ẹyẹ mẹ́rin fẹ́ lọ mu omi.
Three buffaloes and four birds going for a drink of water too.
Three buffaloes and four birds are also going to drink water.
EbonicsYorùbáEnglish
3
Ẹtu márùnún àti túrùkú mẹ́fà ń rìn lọ sí ibi omi.
Five impalas and six warthogs walking they way to the water.
Five impalas and six warthogs are walking to the water.
EbonicsYorùbáEnglish
4
Sẹ́bírà méje ń sáré lọ mu omi.
Seven zebras running to the water.
Seven zebras are running to the water.
EbonicsYorùbáEnglish
5
Kọ̀ǹkọ̀ mẹ́jọ àti ẹja mẹ́sànàn ń wẹ̀ nínú omi.
Eight frogs and nine fish swimming in the water.
Eight frogs and nine fish are swimming in the water.
EbonicsYorùbáEnglish
6
Kìnìún kan bú ramúramù.

Òun náà fẹ́ mu omi

Tani ń bẹ̀rù kìnìún?
One lion roars.

He finna drink too.

Who there afraid of the lion?
One lion roars.

He also wants to drink.

Who is afraid of the lion?
EbonicsYorùbáEnglish
7
Erin kan ń mu omi pẹ̀lú kìnìún.
One elephant drinking water with the lion.
One elephant is drinking water with the lion.
EbonicsYorùbáEnglish
8
The end.
Counting Them Animals